Tope Alabi – Yes And Amen

MP3 DOWNLOAD

Tope Alabi – Yes And Amen

Tope Alabi Yes And Amen Mp3

Tope Alabi Yes And Amen Mp3 Download Fakaza Gospel. Enrich your soul with the latest Gospel music representation by Tope Alabi in her latest single Yes And Amen.

MP3 DOWNLOAD

Tope Alabi Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD MP3: Tope Alabi – Yes And Amen

Lyrics: Yes And Amen

Amin Ase ida a lamo o
Eni ti o ni a padanu
Iba o to to olu Imo o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Amin aseda
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
(Ko ni nkankan)
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
Oooooooo
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
E ko ni nkankan oMo wa ri foba to ni di da aiye eeee
Ibare mare e, oni gbede orun
Iwo to ni gbogbo aiye ni ikawo
Bo ti doyi kato
Iba oni mo to ga ju ee
Baba ni baba se
Amin ase ida mo gbe ba fun
Amin ase ida la mo o
Eni ti o ni o ke
Eni ti o ni a padanu
Adanu nla lo pa laye, lorun
Iba o toto olu imo
A ton ton to, mo ri ba, mori ba o
Eni ti o ni o ko ni nkankan
Ko ni nkankan
Eni ti o ni o ko ni nkankan o
E ma ni penre labo
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
Ko ni kini nkan lagbon
Eni ti o ni o, ko ni nkankan o
O tan fun laiye lorun o
Eni ti o ni o EeKo ni nkankanO da okun, O da oosa
Alara to fi omi se osho
Iwo to mo ibi eja gba do odo
Majemu to bu ko ja okun
Iyanrin te ka aiye
O da okunkun biri mu
Oga imole oo
Oju orun o ni ilekun oo
Ogbe bi mejeeji, lai rin irin ajo
O mu eda gba inu eda waiye
Ibi emi ngba lo ba, eni kan o mo
Ajulo o eni ti o wa oKo le mo nkankan
Eni ti o wa ke oEni ti o ni o, ko ni nkankan o
Ko ri nkankan o o
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
Afoju san ju oni to hun lo mo gba
Eni ti o ni o, ko ni nkankanEe
Eni ti o ni o, ko ni nkankan
EeeMajemu alai lepin n lo je
Ijinle alaile tun wo
Irawo nyo lailai lo nka beni
Osupa nse atokun to ba dale beni o
Ibi gbogbo la n ti mi ri beni
O to lo fara da orun saiye beni o
O se ojo otun so da eran beni
Osuwon bi oye, otun sotutu beni o
Eranko Igbo won lo su a beni
Eweko, ewebe igi iyen o se sawa ri na
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o
Eni ti o ri se e, ko ri nkan
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan
Ko da ko ri ra e pa be ni
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan o
Ooo
Eni ti o ri se e, ko ri nkankan…
Beat…
Ose mi da bi ohun, opin mi ni ipin
Ti ko Jo ti eni keji
Mi o la le hu, emi ni ami aseda latorun
Adagbeyin ni mi o wa fi mi joba
Ohun gbogbo ti o ti ko da
Odami ofunmi ni re
Emi ni beeni, ase olodumare ni
Amin lohun, emi lami
Ayanmo ogo, Ogun mi ni
Eda emi lo fi se ranse mi
Akori Iran mi, oju ogo re niMo ni imi ye re ninu
Eni o ri mi, ko ri nkankan
Eee Eni ti o ri mi
Ko ri nkankan.Eni ti o ri mi
Ko rise olorun wo
E Eni ti o ri mi ke, ko ri nkan
Eni ti o ri mi
Ko ri nkankan o
E o foju
Eni ti o ri mi, ko rise olorun woKo ri olodumare, oda mi bi ohun ni
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan
Eni ti o ri mi, ko ri se olorun wo
Ooooooo
Eni ti o ri mi, ko ri nkankan oEni ti o ri mi, ko ri se olorun wo
Eni ti o ri mi ko ri nkankan
Ami lawa je, si Iwo amin
Beni ire loje ki aiye wa oOlorun la min
Amin lon famin wa han
Aiye, atorun lamin yen o
Aseda ni amin
Oro re lo je ki a ma wa
Olorun la minAmin, Amin, Amin, Amin oTranslate to English