Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Tope Alabi Loro Lero Ati Nise Mp3

Tope Alabi Loro Lero Ati Nise Mp3 Download Fakaza Gospel. Veteran Nigerian gospel singer, Tope Alabi unveils this soothing anthem is rife with energy and powerful beats captioned Loro Lero Ati Nise.

Tope Alabi Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD Mp3: Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Lyrics: Tope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Verse 1
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chrous:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise