Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Tope Alabi Eyin Oluwa Halleluyah Mp3

Tope Alabi Eyin Oluwa Halleluyah Mp3 Download Fakaza Gospel. Tope Alabi has Etched out sheer brilliance in the splendid Gospel music dubbed Eyin Oluwa Halleluyah.

Tope Alabi Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD Mp3: Tope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Lyrics: Eyin Oluwa Halleluyah

Verse 1
Eje ka f;ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai

Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah

Verse 2
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

Verse 3
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo

Verse 4
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo