Motunrayo Adewoyin – Awamaridi

MP3 DOWNLOAD

Motunrayo Adewoyin – Awamaridi

Motunrayo Adewoyin Awamaridi Mp3

Motunrayo Adewoyin Awamaridi Mp3 Download Fakaza Gospel. Motunrayo Adewoyin comes to spotlight with an amazing single titled Awamaridi.

MP3 DOWNLOAD

Motunrayo Adewoyin Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD Mp3: Motunrayo Adewoyin – Awamaridi

Lyrics: Awamaridi

Iba’koda aye
Iba’seda orun
Iba’koda aye
Iba’seda orun
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

Iba’koda aye
Iba’seda orun
Iba’koda aye
Iba’seda orun
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

E wole f’oba, Ologo julo
E korin ipa ati ife Re
Alabo wa ni, at’Eni igbani
O ngbe ‘nu ogo Eleru ni iyin

Oke nla ti n ka satani laya,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya
Oke nla ti n ka satani laya o,
Ohun eni ti n fa igi kedari ya

Eru re n ba mi o,
Mo’laya re n pa mi.
Eru re n ba mi o,
Aya re n pa mi.
Awamaridi eledumare, oba mi toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba.

Eru re n ba mi o,
Mo’laya re n pa mi.
Eru re n ba mi o,
Aya re n pa mi.
Awamaridi eledumare, oba mi toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba o.

Awamaridi eledumareee, eni nla toto fi’se ogun ran
Awamaridi eledumare, baami atonigba o.
Awaaa…..maridi…… eni toto fi’se ogun ran
Awa a ko ridi re o, baami atonigba o.
Awaaa…..o eni toto fi’se ogun ran
Awa, ao ridi re o, baami atonigba o.