Laolu Gbenjo – EverGreen Yoruba Medley

Laolu Gbenjo – EverGreen Yoruba Medley

Laolu Gbenjo EverGreen Yoruba Medley Mp3

Laolu Gbenjo EverGreen Yoruba Medley Mp3 Download Fakaza Gospel. Laolu Gbenjo comes to spotlight with an amazing single titled EverGreen Yoruba Medley.

Laolu Gbenjo Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD Mp3: Laolu Gbenjo – EverGreen Yoruba Medley

Lyrics: EverGreen Yoruba Medley

Lẹ’yìn Jésù ko sẹ’ ni kán o
Ọba mímọ l’ọ’ba t’emi n sin
Lẹ’yìn Jésù ko sẹ’ ni kán o
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Lẹ’yìn Jésù kò má sẹ’ ni kán o
Ọba mímọ l’ọ’ba t’emi n sìn nígbà gbogbo lojojumọ’
Lẹ’yìn Jésù ko má sẹ’ ni kán o
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Lẹ’yìn Jésù ni mímọ
Lẹ’yìn Jésù ko sẹ’ ni kán ó (Ọba mímọ má ni)
Ọba mímọ l’ọ’ba tí mo n sìn (Lẹ’yìn Jésù)
Lẹ’yìn Jésù ko sẹ’ ni kán ó (Alágbára gíga ní o)
Alágbára mo mọ ‘rukọ rẹ
Jésù olùtọ́jú ènìyàn
Alágbára gíga-gíga gíga-gíga
Lọrun àti láyé bàbà mi mímọ o
Òdì kan gbé rẹ ni ja
Ọlọ’wọ’gbọgbọrọ tí ń yọ mọ rẹ lofin ayé
Àárín má tọ’ka lẹ’yìn
Ogberin lẹ’yìn aṣo’ dodo bàbá Mímọ’
Sárà rẹ náà re
Baba olùtọ́jú ènìyàn
Sárà rẹ náà re
Olùtọ́jú mi nígbà gbogbo ẹ ṣé o
Jésù olùtọ́jú ènìyàn (Sárà rẹ ó ooo)
Sárà rẹ náà rẹ (Atobajaiye Elédùmarè bàbà mimọ)
Baba olùtọ́jú ènìyàn (Eh Sárà rẹ)
Sárà rẹ náà re
Èmi o màmà rí ọ rí o
Ọlọ’run mi
Ṣùgbọ’n mo rí ‘ṣẹ rẹ nínú ayé mi
Èmi o màmà rí ọ rí o
Ẹlẹ́dàá mi
Ṣùgbọ’n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi bàbà o Eh!
I have assurance Ọlọ́run mi bàbà mímọ
Wípé ẹ wa
I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa
Èmi o rí ọ rí o Ọlọ’run mi
Ṣùgbọ’n mo rí ‘ṣẹ rẹ (Ṣùgbọ́n mo rí àánú rẹ nínú ayé mi mo rí’ ọwọ rẹ bàbà mímọ)
Èmi o rí ọ rí o Ọlọ’run mi
Ṣùgbọ’n mo rí ‘ṣẹ rẹ
La la la la la la la la Olúwa o
I have assurance Ọlọ́run mi
Wípé ẹ wa
I have assurance Ọlọ́run mi wípé ẹ wa
Ọlọ’run mi
Ọlọ’run mi
Ìwọ lójú tí mo fí ń ríran
Ìwọ ni kọ’kọ’rọ’ tí mo fi ń ṣílẹ̀kùn
Ìwọ l ‘orin tí mo ń kọ eh
Ina ayé ẹ ò jẹ’ kó jo mi
Kí ni mo ní ti mo lè fún ọ o
Mo wólẹ’ mo ki ọ ó bàbà
Ọlọ’run mi
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe’ yanu rẹ lórí mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Àní Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe’ yanu rẹ lórí mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga pupọ
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe’ yanu rẹ láyé mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Ìgbà tí mo rò ó
Ìṣe’ yanu rẹ láyé mi
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga
Mo rí pé ó ga Bàbá
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà ooo
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà
(O f’aye mi dà bí rà dá bí rà)
(O f’aye mi dà bí rà dá bí rà)
(Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi)
(Ṣáá má wo mí ẹ rọra wo mi)
Edumare f’ayé mi dá bí rà sẹ o
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà o
Lójú ọ’tá mi o gbé mi lékè
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà
Lójú ẹlẹ’tan ó wá s’ẹkún mi d’ẹ’rín ṣẹ oo
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà
Ó ra mi padà ó wà sọ mé d ‘ọmọ rẹ Eledumare Ẹ ṣé o
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà
Lójú ọ’tá mi o gbé mi lékè
Bàbá ń f’aye mi dá bí rà