Sola Allyson – Mo Ki O

Sola Allyson – Mo Ki O Mp3 download

Sola Allyson Mo Ki O Mp3

Sola Allyson Mo Ki O Mp3 Download Fakaza Gospel. The Nigerian gospel singer and songwriter, Sola Allyson thrills her fan with an exceptional gospel melody titled Mo Ki O.

Sola Allyson Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD MP3 Sola Allyson – Mo Ki O

Mo Ki O Lyrics By Sola Allyson

Call: Mo Ki o ki o olorun gbo gbo eniyan ti n be ninu aye
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Mo Ki o ki o olorun to wa lori ite nibiti imole wa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Oooolorun olugbo adura gbogbo eniyan ti n be ninu aye oooo
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Awa maridi ti o se n salaye loun kan olorun iseda
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Olorun ti gbogbo ede ti gbogbo eya n ke be ogo ni foruko re
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Aseda gbogbo eniyan oloore iseda
Response: Olorun gbogbo eran ara
Solo: Tani maa ki bi o se iwo
Tani maa sin bi o se iwo
Tani o to n ki bi o se iwo
Tani o to n sin bi o sent iwo
Iwo lo da aye ati orun
Oun ti o n mi ise re ni
Eyi ti o mi n bu ola fun o
Iwo ni olorun gbogbo aye
Iwo ni olorun oun gbogbo
Iwo ni olorun gbogbo aye
Iwo ni olorun Oun gbogbo
Call: Mo ki o ki o olorun gbogbo eniyan ti n be ninu aye oooo
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Mo Ki o ki o olorun to wa lori ite lohun nibiti imole wa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Ninu imole to nilo fun lo ati eni to
Mo o ati eni ti o mo o lo n je anfani ise re
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Ati alawo dudu ati alawo fun fun
Ise re ni gbogbo wa a n yin o lohun kan oluwa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Iwo ni Oba olupese Oba Olola Oba oloore
Oba oloore gbogbo Ebun lati odo re lo ti wa baba aaa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Olorun olugbo Adura gbogbo eniyan ti n be ninu aye oo
Response: Olorun gbogbo eran ara
Solo: Iwo to fe wa la n sin
Iwo to fe wa la n bo
Ko to da wa loti pese si le
Gbogbo ohun ta n ri lo lanri
Eweko n dagba fun jije wa
Ta lo mo orisun ibi ti omi ti n jade
Iwo ni olorun gbogbo aye
Iwo ni olorun oun gbogbo
Iwo ni olorun gbogbo aye
Iwo ni olorun Oun gbogbo
Call: Mo Ki o ki o olorun gbo gbo eniyan to wa lori ile yi aye ka
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Oooolorun olugbo adura gbogbo eniyan ti n be ninu aye oooo
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Call: Mo Ki o ki o olorun to wa lori ite lohun nibiti imole wa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Egbegberun awon Irawo n tan imole
Fun anfani ise re ni fun ogo re ni oluwawa
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Orun ran osupa wa Imole n tan ogo ni foruko re won yin o logo
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: Olorun lati ogbun okan mi ogo ni
Foruko re emi n ko orin ti ogbon ori mi o le ko
Response: Olorun gbogbo eran ara
Call: imole n tan
Response: Okunkun n su
Call: anfani n be