Sola Allyson – Imole II (Acoustics)

Sola Allyson – Imole II (Acoustics) Mp3 download

Sola Allyson Imole II (Acoustics) Mp3

Sola Allyson Imole II (Acoustics) Mp3 Download Fakaza Gospel. The Nigerian gospel singer and songwriter, Sola Allyson releases the Acoustics version of this song titled Imole II.

Sola Allyson Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD MP3 Sola Allyson – Imole II (Acoustics)

Imole II (Acoustics) Lyrics By Sola Allyson

Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S’ibi Imole
Jesu! Eni t’O wa
Ife Baba
S’eni to fe d’omo
Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S’ibi Imole
Jesu! Eni t’O wa
Ife Baba
S’eni to fe d’omo
Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S’ibi Imole
Jesu! Eni t’O wa
Ife Baba
S’eni to fe d’omo
Imole, lati ‘nu Imole
O wa lati da wa pada
S’ona Imole
Ookun to gb’ aye
Ko je k’ ‘on mo Imole
Won dite mo O, Ife Baba
Olorun ninu eniyan
Eniyan ninu Olorun
Ilekun awon aguntan
S’inu ile aanu
Ipase eni ti mo gba igbala ati ilaja s’odo Baba
B’ aye ti n fi fun ni ko
Imole s’ookun aye mi
Olu se ‘wosan emi mi
Jesu! Imole!
Ategun ati Afara
S’ibi Imole
Jesu! Eni t’O wa
Ife Baba
S’eni to fe d’omo
Jesu! Imole!
Ategun ati afara
S’ibi Imole
Jesu! Eni t’O wa
Ife Baba
S’eni to fe d’omo
Eni wa Imole
Won n ri Imole
Won o mo Imole
Won n dite Imole
Irora yen po gan
Eje at’ omi san gan
Sibe O s’ agbawi fun wa
Pe Baba dariji won
Won o mo n t’ ‘on se
S’ a ti mo ‘n a n se
Baba, dariji wa o, nitori Imole
Ninu irora Re, o tun fi iyonu mu ole ***
O ni “Iya wo omo re, Omo wo iya Re”
O kigbe lohun rara:
“Olorun mi, eese t’ O ko mi i le…”
“Eese to ju mi le, eese t’ O yin mi nu?”
Oungbe po gan, oti kikan laye fun Un
Awon to wa Imole o, won fi ‘ya je Imole
O ba pari, O pari!
Imole f’ emi E s’owo Baba
O pari!
Nitori Imole
Aso ikele ya o
Nitori Imole
A le pe Baba ni Baba
Nitori Imole
Isa oku d’ofo
Eni ba fe le wa d’omo
Jesu! Oga Ogo!
Olori Ogun Orun!
Omo Alade Alaafia!
Alase Orun!
Aye Baba!
Baba laaye o!
Baba laye!
Aye mi, Tire ni
Tan Imole nipase mi
Ogo mi k’o f’ogo fun O
Ola mi k’o bu ola fun O!
Jesu! Iwo ni ‘Mole!
Iwo ni Afara!
S’ibi ategun Imole
Jesu! Iwo ni Eni naa t’O wa
Mo juba Re, Eni to so mi d’omo