Sola Allyson – Ayò Dé

Sola Allyson – Ayò Dé Mp3 download

Sola Allyson Ayò Dé Mp3

Sola Allyson Ayò Dé  Mp3 Download Fakaza Gospel. The Nigerian gospel singer and songwriter, Sola Allyson thrills her fan with an exceptional gospel melody titled Ayò Dé.

Sola Allyson Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD MP3 Sola Allyson – Ayò Dé

Ayò Dé Lyrics By Sola Allyson

Oya, e je ki a gbadura
Adura n gba, apemora eni la n pe temidire
Ayo de o, ayo de o, ayo de
Ibukun wole o, ibukun wole o, ibukun wole
Imole ti wa o, imole ti wa o, imole ti wa
Oba gbe ‘re de o, Oba mu ‘re wa o, ire ti de
I am a joy child so I have joy, ayo de o
I am a blessed child, yes I am blessed to po gan, Ibukun wole
From the highest height, imole tan sori mi, imole ti wa o
I am a light shining, my path is bright gan ni, imole ti wa o
Ayo de o, ayo de o, ayo de
I am a joy child, I have joy, aye mi kun gidi gan ni, beeni, ko le tan
I am a blessed child, so I am blessed, ibukun po lona mi gan ni
I am a light shining, so I am light, imole mi o ni ku lailailailailai
Lat’oke lohun lo ti n tan wa sori iseda mi, ko sohun to le da a duro
I am joy, I have joy
I am a channel of joy
Ayo de
I am blessed, ibukun n mo je, mo ni ibukun to po, ibukun wole
I am light, I have light, I shine bright, imole ti wa
What can stand against me, orun wa leyin mi, ayo de
Ayo de o, ayo de o, ayo de
Ibukun wole o, ibukun wole o, ibukun wole
Imole ti wa o, imole ti wa o, imole ti wa
Oba gbe ‘re de o, Oba mu ‘re wa o, ire ti de
Amin ooo, bee naa la ri o, ase!
Bee naa la ri o.