Bunmi Akinnanu – Mo Ti Ranu Gba

Bunmi Akinnanu – Mo Ti Ranu Gba Mp3 download

Bunmi Akinnanu Mo Ti Ranu Gba Mp3

Bunmi Akinnanu Mo Ti Ranu Gba Mp3 Download Fakaza Gospel. The Renowned Nigerian Gospel Music Minister, Bunmi Akinnanu releases another brand new amazing gospel melody titled Mo Ti Ranu Gba.

Bunmi Akinnanu Mp3 Download. Listen online, and enjoy The Lyrics, Video of your favorite Music

Stream, Listen, and Download Below.

DOWNLOAD MP3 Bunmi Akinnanu – Mo Ti Ranu Gba

Mo Ti Ranu Gba Lyrics By Bunmi Akinnanu
Ma soreti nu omo tuju ka
Oro re ko ti to ki o ro ra re pin
Ma lo sare moto ko lu keke o
O somo oloku bee ni
Wa ye eh eh
Ma sokun mo ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Ma sokun mo (ma banuje) ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Ma ba nu je ore mi o
Omije oju re baba yo fi sogo ni (ore mi o)
Ma sokun mo ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Ise to se o fogun odun
Iya to je o fopo osu
bi ko ba ti gbemi re
wa fi se itan rere pa
Ma sokun mo ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Jesu ko ni fi o sile ore ma sokun mo
Eyin oju ni o lowo olorun
ko lo mu suru
Ma sokun mo ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Ma lo sare moto kolu keke
wa kuku ye eh
Eyin oju ni o lowo olorun
wa bori isoro
Ma sokun mo ore mi o
Ibanuje aye re fun o igba die ni
Wa na onigbagbo o lo tuju ka
Aisepade olosi ko je a mo iya awon ise o
Ma lo sare moto kolu keke o
O se omo oloku bee ni
wa a ye e
Ibanuje inu aye re o
fun o igba die ni
Suuru to lojo ni idamu re
ko ni koja afarada
ki Jesu to dide
A o riru eleyi ri
eru la n da ba oloran